Yoruba Updated on Dec 6, 2020 by Isaac InegbenehiDec 6, 2020 Welcome to Flashlearners Yoruba Quiz... Read Each Question Carefully And Choose The Best Answer From The Options. You May Click Here for Free Video Tutorials To Boost Your Score Or Simply Click Here To Access Thousands of Yoruba Questions Offline. Next To Begin...1. LÍTÍRÉßÕÌwé Ojú Òÿùpá, apá kìíní ni ìbéèrè dá lé.Nínú ìtàn Ìtànÿan Oòrùn … lëyìn bí ôjö mélòó ni Êsankígbé tó tú àÿírí ôba fún baba rê?MéjìMëtaMërinMëfà2. Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wônÔba Fadérera ní oko kòkó àti oko obì, ó ní oko iÿu àti oko òwú, ilá inú oko rè ni gbogbo ìlú gbójú lé, iÿu àkùrõ rê níí kökö yôjú sí ôjà. Oko ôba gbòòrò púpõ.Sé ìgbà púpõ ni õpõlôpõ ènìyàn þ lô láti ÿiÿç õfë fún ôba. Ôba tún fi ôgbôn ÿe é tó bëê tí irè oko rê kò wön tó ti çlòmíràn.Ôba Fadérera bí ômôkùnrin kan tí ó fëràn púpõ. Ômô ôba yìí kì í ÿe iÿë kankan, àfi ki ó máa ÿiré nínu ôgbà baba rê. Àwôn ìránÿë põ láti fún un ní gbogbo ohun tí ó bá þ fë. Aÿô tuntun ni ômô ôba þ wõ ní ojoojúmö. Ôba kë ômô náà bí çyin ojú, ó kë ç pêlú ohun ìní àti ìránÿë.Ohun kan wá jë êdùn ôkàn àwôn ará ìlú Êyìn-Õla. Ohun náà ni pé, ìkòokò a máa dédé wô ìlú láti gbé ewúrë tàbí àgùntàn wôn lô. Ní ìgbà púpõ ni àwôn ará ìlú ti lô ké bá ôba kí ó bá àwôn yanjú õràn tí ó dé bá wôn. Nígbà tí ó ÿe wàyí o, àwôn ìkòokò pàápàá wá tún ara mú, wön bêrê sí í gbé àwôn ômô ará ìlú Êyìn-õla. Àwôn ìlú tún ké lô sí õdõ õba, ÿùgbön ôba kò ka õrõ náà sí rárá.Ní ôjö kan nígbà tí ômô ôba Fadérera àti àwôn çmêwà bàbá rê þ ÿiré lórí pápá tí ó wà lëbàá ààfin, ìkòokò þlá kan yô sí wôn, ó sì gbé ômô ôba lô ráúráú. Nígbà tí ôba gbö ohun tí ó ÿçlê, ó kígbe ní ohùn rara.Õrõ náà wá ya gbogbo ìlú lënu nítorí pé ôba pàÿç lësêkçsê pé kí gbogbo àwôn ôdç atamátàsé ìlú jáde, kí wön sì pa gbogbo ìkòokò tí ó wà agbègbè náà. Sùgbön ìkòokò tí pa ômô ôba Fadérera jç. Êpa kò bóró mö.Kí ni ó fún Ôba Fadérera lólìkí?Ìwà rere rêOko iÿu rêÇwà rêIrè oko rê3. Õkan lára ohun-èlò ti Yorùbá fi máa þ ÿe õÿö sí ara ômô tuntun niÌßÊßElàálìòríosùnbùjé4. Çgbë-n-bígbo, àbí àjùmõ-gbélé-põ?ÌßÊßEÇgbë-n-bígbo, àbí àjùmõ-gbélé-põ?Ta ló lè pèdè yìí síni?ÕrëAjunilôOjúgbà çniÔmô-çgbë çni5. Àbùdá ômôlúàbí ni kí óÌßÊßEÀbùdá ômôlúàbí ni kí ósõrõ láwùjôbá àgbà sõrõ pêlú pákò lënujókòó nígbà tí àgbà wà ní ìdúróbõwõ fénìyàn6. Èwo nínú ìwõnyi ló ní möfíìmù ìÿêdá kan?ÈDÈÈwo nínú ìwõnyi ló ní möfíìmù ìÿêdá kan?ElégboAlágbeÔlõtêÇlëbí7. ße ìtumõ ‘Uneasy lies the head that wears a crown’ÈDÈÕpõlôpõ ìdààmú wà lórí tó dé adéÕpõlõpõ wàhálà ló rõ mö ipò olóríÕpõlôpõ ìdààmú ló ÿe àtakò olóríÕpõlôpõ wàhálà dúró lórí tó dé adé8. Ète môfölõjì tí a lò láti ÿêdá ômôkömô niÈDÈàpètúnpèàpètúnpè pêlú àfòmö-ìbêrêàkànpõàpètúnpè pêlú àfòmö-ààrin9. Òdiwõn ojúgbà láàrin ìlú niÌßÊßEyíyagìrìpáagbáraôjö oríôlá10. Èwo ni ó fi ìgbàgbö Yorùbá nípa ayé lëyìn ikú hàn nínú ìwònyí?ÌßÊßEÈwo ni ó fi ìgbàgbö Yorùbá nípa ayé lëyìn ikú hàn nínú ìwònyí?Ôdún egúngúnÔdún ògúnÌÿípà ôdçÀàrò kíkó11. ÈDÈÕrõ wo ni kò ní apààlà sílébù nínú Olú á ra bàtà?Olúárabàtà12. Àpççrç õrõ àyálò níbi tí köþsónáýtì ti parí õrõ niÈDÈmáþgòròtöõgìbíròbúlúù13. Bí F1 bá jë e, F2 yóò jëÈDÈBí F1 bá jë e, F2 yóò jëçnôônu14. Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wônBabárìndé nífêë Fôláÿadé púpõ. Fôláÿadé náà sì rèé, òrékelëwà ômôge, çlëyinjú-çgë, çlërin-ín êyç! Òun náà sì dá ìfë yìí padà pêlú ayõ àti ìdùnnú. ßùgbön bàbá Fôláÿadé ni igi wörökö tí þ da iná rú nídìí õrõ yìí: ó kórìíra Babárìndé nítorí pé ó kà á sí òtòÿì ènìyàn.Bëê ômôlójú rê sì ni Fôláÿadé í ÿe. Baba gbàgbö pé bí ômô òun bá fë Babárìndé, inú ìyà ni tôkôtaya wôn yóò wà.Kì í kúkú í ÿe pé Babárìndé jë tálákà bëê náà: ó þ ÿiÿë gëgë bí òÿìÿë kékeré nílé-iÿë þlá kan, bëê ni kò sì tôrô jç, ÿùgbön ó kàn jë pé kò lówó tó Ayõkúnlé Atáyéwá, oníÿòwò kan tí baba Fôláÿadé fë kí ômô rê fë. Ìyá Fôláÿadé náà sì rèé, ibi tí ôkô rê bá tê sí ni òun náà þ tê sí. ßé ojúbõrõ kö ni a sì fi þ gbômô löwö èkùrö: àwôn òbí Fôláÿadé fi toògùn-toògùn fa ômô wôn fún Ayõkúnlé Atáyéwá ÿaya. Babárìndé banújë nídìí õrõ yìí, êdùn-ôkàn sì ni Fôláÿadé gbé wôlé ôkô.Ôjö þ gorí ôjö, ôdún þ gorí ôdún, bëê ni ìgbà sì þ rékôjá lo. Fôláÿadé bí akô, ó bi abo nílé ôkô, ÿúgbön nýkan ò lô déédé fún ôkô rê mö lënu òwò rè. Àwôn oníbodè ti gbësê lé ôjà rê tó jë çgbêlëgbê náírà. Ó yáwó nílé-ìfowópamö, ÿùgbön kò rí i san padà. Àwôn báýkì bá gba ilé, ôkõ àti àwôn dúkìá rê mìíràn. Àtijç-àtimu wá di ìÿòro fún òun àti ìyàwó rê àti àwon ômô wôn pêlú.Níhà kejì, Babárìndé náà ti gbéyàwó, ó sì tí bímô. Lënu iÿë rê wàyìí, ó ti di õgá, orí sì ti sún un sölá. Àwôn òbí Fôláÿadé wá þ wò sùnùn, wön rí i bí ìgbé-ayé Ayõkúnlé Atáyéwá ÿe þ lô, wön sì tún wo ti Fôláÿadé ômô wôn, bákan náà ni wön sì þ gbókèèrè wo ti Babárìndé bó ÿe þ dùn sí i fún un. Wön wá fika àbámò bônu: iwájú ò ÿeé lô, èyìn ò sì ÿeé padà sí fún wôn. Babárìndé, eni tí wôn rò pé kò lè pàgö ló wá dçni tí þ kölé aláruru. Ó wá hàn kedere sí wôn pé çni tí yóò dôlölà löla, orí ló mõ ön.Êkö pàtàkì tí àyôkà yìí köni ni péoògùn máa þ jëêda kò láròpinagbaniláya ò rore sínikí a máa fõrõ rora çni wò15. ÈDÈÌrókíròó tí a bá pè nígbà ti ìdíwö wà fún èémí nifáwêlìköþsónáýtììró-ohùnìró-ìfõ16. Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.Babárìndé nífêë Fôláÿadé púpõ. Fôláÿadé náà sì rèé, òrékelëwà ômôge, çlëyinjú-çgë, çlërin-ín êyç! Òun náà sì dá ìfë yìí padà pêlú ayõ àti ìdùnnú. ßùgbön bàbá Fôláÿadé ni igi wörökö tí þ da iná rú nídìí õrõ yìí: ó kórìíra Babárìndé nítorí pé ó kà á sí òtòÿì ènìyàn.Bëê ômôlójú rê sì ni Fôláÿadé í ÿe. Baba gbàgbö pé bí ômô òun bá fë Babárìndé, inú ìyà ni tôkôtaya wôn yóò wà.Kì í kúkú í ÿe pé Babárìndé jë tálákà bëê náà: ó þ ÿiÿë gëgë bí òÿìÿë kékeré nílé-iÿë þlá kan, bëê ni kò sì tôrô jç, ÿùgbön ó kàn jë pé kò lówó tó Ayõkúnlé Atáyéwá, oníÿòwò kan tí baba Fôláÿadé fë kí ômô rê fë. Ìyá Fôláÿadé náà sì rèé, ibi tí ôkô rê bá tê sí ni òun náà þ tê sí. ßé ojúbõrõ kö ni a sì fi þ gbômô löwö èkùrö: àwôn òbí Fôláÿadé fi toògùn-toògùn fa ômô wôn fún Ayõkúnlé Atáyéwá ÿaya. Babárìndé banújë nídìí õrõ yìí, êdùn-ôkàn sì ni Fôláÿadé gbé wôlé ôkô.Ôjö þ gorí ôjö, ôdún þ gorí ôdún, bëê ni ìgbà sì þ rékôjá lo. Fôláÿadé bí akô, ó bi abo nílé ôkô, ÿúgbön nýkan ò lô déédé fún ôkô rê mö lënu òwò rè. Àwôn oníbodè ti gbësê lé ôjà rê tó jë çgbêlëgbê náírà. Ó yáwó nílé-ìfowópamö, ÿùgbön kò rí i san padà. Àwôn báýkì bá gba ilé, ôkõ àti àwôn dúkìá rê mìíràn. Àtijç-àtimu wá di ìÿòro fún òun àti ìyàwó rê àti àwon ômô wôn pêlú.Níhà kejì, Babárìndé náà ti gbéyàwó, ó sì tí bímô. Lënu iÿë rê wàyìí, ó ti di õgá, orí sì ti sún un sölá. Àwôn òbí Fôláÿadé wá þ wò sùnùn, wön rí i bí ìgbé-ayé Ayõkúnlé Atáyéwá ÿe þ lô, wön sì tún wo ti Fôláÿadé ômô wôn, bákan náà ni wön sì þ gbókèèrè wo ti Babárìndé bó ÿe þ dùn sí i fún un. Wön wá fika àbámò bônu: iwájú ò ÿeé lô, èyìn ò sì ÿeé padà sí fún wôn. Babárìndé, eni tí wôn rò pé kò lè pàgö ló wá dçni tí þ kölé aláruru. Ó wá hàn kedere sí wôn pé çni tí yóò dôlölà löla, orí ló mõ ön.Ohun tó mú àyípadà burúkú bá Atáyéwá ni péó yáwó nílé-ìfowópamökõ jára möÿë möòwò rê lô sílêwön ÿàkóbá fún un17. Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.Babárìndé nífêë Fôláÿadé púpõ. Fôláÿadé náà sì rèé, òrékelëwà ômôge, çlëyinjú-çgë, çlërin-ín êyç! Òun náà sì dá ìfë yìí padà pêlú ayõ àti ìdùnnú. ßùgbön bàbá Fôláÿadé ni igi wörökö tí þ da iná rú nídìí õrõ yìí: ó kórìíra Babárìndé nítorí pé ó kà á sí òtòÿì ènìyàn.Bëê ômôlójú rê sì ni Fôláÿadé í ÿe. Baba gbàgbö pé bí ômô òun bá fë Babárìndé, inú ìyà ni tôkôtaya wôn yóò wà.Kì í kúkú í ÿe pé Babárìndé jë tálákà bëê náà: ó þ ÿiÿë gëgë bí òÿìÿë kékeré nílé-iÿë þlá kan, bëê ni kò sì tôrô jç, ÿùgbön ó kàn jë pé kò lówó tó Ayõkúnlé Atáyéwá, oníÿòwò kan tí baba Fôláÿadé fë kí ômô rê fë. Ìyá Fôláÿadé náà sì rèé, ibi tí ôkô rê bá tê sí ni òun náà þ tê sí. ßé ojúbõrõ kö ni a sì fi þ gbômô löwö èkùrö: àwôn òbí Fôláÿadé fi toògùn-toògùn fa ômô wôn fún Ayõkúnlé Atáyéwá ÿaya. Babárìndé banújë nídìí õrõ yìí, êdùn-ôkàn sì ni Fôláÿadé gbé wôlé ôkô.Ôjö þ gorí ôjö, ôdún þ gorí ôdún, bëê ni ìgbà sì þ rékôjá lo. Fôláÿadé bí akô, ó bi abo nílé ôkô, ÿúgbön nýkan ò lô déédé fún ôkô rê mö lënu òwò rè. Àwôn oníbodè ti gbësê lé ôjà rê tó jë çgbêlëgbê náírà. Ó yáwó nílé-ìfowópamö, ÿùgbön kò rí i san padà. Àwôn báýkì bá gba ilé, ôkõ àti àwôn dúkìá rê mìíràn. Àtijç-àtimu wá di ìÿòro fún òun àti ìyàwó rê àti àwon ômô wôn pêlú.Níhà kejì, Babárìndé náà ti gbéyàwó, ó sì tí bímô. Lënu iÿë rê wàyìí, ó ti di õgá, orí sì ti sún un sölá. Àwôn òbí Fôláÿadé wá þ wò sùnùn, wön rí i bí ìgbé-ayé Ayõkúnlé Atáyéwá ÿe þ lô, wön sì tún wo ti Fôláÿadé ômô wôn, bákan náà ni wön sì þ gbókèèrè wo ti Babárìndé bó ÿe þ dùn sí i fún un. Wön wá fika àbámò bônu: iwájú ò ÿeé lô, èyìn ò sì ÿeé padà sí fún wôn. Babárìndé, eni tí wôn rò pé kò lè pàgö ló wá dçni tí þ kölé aláruru. Ó wá hàn kedere sí wôn pé çni tí yóò dôlölà löla, orí ló mõ ön.Fôláÿadé gbé êdùn-ôkàn wôlékô nítorí pénþkan kò lô déédéfún ôkô rêkò lè fë çni tó wù ú lökànó rí i pé ìyà þ bç níwájúkò wôlé ôkô nígbà tó wù ú18. Dídá àásó çwà sí wöpõ láàrin àwônÌßÊßEDídá àásó çwà sí wöpõ láàrin àwônõdökùnrinõdöbiýrinàgbà ôkùnrinàgbà obiýrin19. Èwo ni ìgbésê àkökö nínú àÿà ìgbéyàwó?ÌßÊßEÈwo ni ìgbésê àkökö nínú àÿà ìgbéyàwó?ÌwádìíÌfojúsódeÌjöhçnÌtôrô20. Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.Ôba Fadérera ní oko kòkó àti oko obì, ó ní oko iÿu àti oko òwú, ilá inú oko rè ni gbogbo ìlú gbójú lé, iÿu àkùrõ rê níí kökö yôjú sí ôjà. Oko ôba gbòòrò púpõ.Sé ìgbà púpõ ni õpõlôpõ ènìyàn þ lô láti ÿiÿç õfë fún ôba. Ôba tún fi ôgbôn ÿe é tó bëê tí irè oko rê kò wön tó ti çlòmíràn.Ôba Fadérera bí ômôkùnrin kan tí ó fëràn púpõ. Ômô ôba yìí kì í ÿe iÿë kankan, àfi ki ó máa ÿiré nínu ôgbà baba rê. Àwôn ìránÿë põ láti fún un ní gbogbo ohun tí ó bá þ fë. Aÿô tuntun ni ômô ôba þ wõ ní ojoojúmö. Ôba kë ômô náà bí çyin ojú, ó kë ç pêlú ohun ìní àti ìránÿë.Ohun kan wá jë êdùn ôkàn àwôn ará ìlú Êyìn-Õla. Ohun náà ni pé, ìkòokò a máa dédé wô ìlú láti gbé ewúrë tàbí àgùntàn wôn lô. Ní ìgbà púpõ ni àwôn ará ìlú ti lô ké bá ôba kí ó bá àwôn yanjú õràn tí ó dé bá wôn. Nígbà tí ó ÿe wàyí o, àwôn ìkòokò pàápàá wá tún ara mú, wön bêrê sí í gbé àwôn ômô ará ìlú Êyìn-õla. Àwôn ìlú tún ké lô sí õdõ õba, ÿùgbön ôba kò ka õrõ náà sí rárá.Ní ôjö kan nígbà tí ômô ôba Fadérera àti àwôn çmêwà bàbá rê þ ÿiré lórí pápá tí ó wà lëbàá ààfin, ìkòokò þlá kan yô sí wôn, ó sì gbé ômô ôba lô ráúráú. Nígbà tí ôba gbö ohun tí ó ÿçlê, ó kígbe ní ohùn rara.Õrõ náà wá ya gbogbo ìlú lënu nítorí pé ôba pàÿç lësêkçsê pé kí gbogbo àwôn ôdç atamátàsé ìlú jáde, kí wön sì pa gbogbo ìkòokò tí ó wà agbègbè náà. Sùgbön ìkòokò tí pa ômô ôba Fadérera jç. Êpa kò bóró mö.Ìtumõ ráúráú nínú àyôkà yìí nitipátipákíakíapátápátátôlàtôlàTime is Up!
Comments
Yoruba — No Comments
HTML tags allowed in your comment: <a href="" title=""> <abbr title=""> <acronym title=""> <b> <blockquote cite=""> <cite> <code> <del datetime=""> <em> <i> <q cite=""> <s> <strike> <strong>